Abstract Amuld ohun-elo ikoni se pataki ninu eto-ikoni niton pe 6 n je ki idanilekoo ni itumo si akekoo ki 6 si ye won ju eyi ti oluko ko 16 won. Wiwo fiimu agbelewo Yoriiba ati sise itupale awon asa ati litireso alohun inu won je ona kan ti oluko le gba ko asa ati litireso alohun. Pupd ninu awon akekoo ode dni ni ko ni imo ti 6 kun lori asa atii litireso alohun Yoruba nitori ko si eko ti 6 peye lori awon koko wonyi ni ile-eko bee ni pupd akekoo ko ka iwe ti a ko lori asa ati litireso alohun Yoruba mo. Ibeere lori asa ati litireso je kan- h-pa fun akekoo lamti dahitn ninu idanwo abajade oniwee mewaa. Meji lara ogopro fiimii agbelewo Yoruba ti beba yiiyan ladyo ni Ar- ugba ati Basorun Gaa. Beba yii se agbeyewd bi fiimu agbelewo Yoruba se here ati awon abuda ti 6 mil un je eka litireso Yoruba. O tun se agbeyewd ohun-elo, asa ati litireso alohun ninu awon fiimu ti a yan ladyo yii. Siwajii si i, beba yii se alaye bi oluko se le fi fiimu yi ko akeko ni asa citi litireso alohun Yoruba. Agbekale beba yii ni 6 waye nipa sise amulo tiori meji ti 6 ba ise yii mu-ifakiyesi-nimb ati ifoju-asd-wd 6 si guhle nipa sise afikun imo pe oju opp oluko litireso Yoruba yob si si ona yii lad ko awon akekoo won ni asa ad litireso alohun Yoriiba.
A.A, A (2021). FllMU AGBELEWO G£GE BI OHUN-ELO IKONI NI A§A ATI LITIRESQ ALOHUN YORUBA: FUMU ARUGBA ATI BA$ORUN GAA GEGE BI AWOTA”. Afribary. Retrieved from https://track.afribary.com/works/fllmu-agbelewo-g-ge-bi-ohun-elo-ikoni-ni-a-a-ati-litiresq-alohun-yoruba-fumu-arugba-ati-ba-orun-gaa-gege-bi-awota
A.A, Adeyinka "FllMU AGBELEWO G£GE BI OHUN-ELO IKONI NI A§A ATI LITIRESQ ALOHUN YORUBA: FUMU ARUGBA ATI BA$ORUN GAA GEGE BI AWOTA”" Afribary. Afribary, 23 Apr. 2021, https://track.afribary.com/works/fllmu-agbelewo-g-ge-bi-ohun-elo-ikoni-ni-a-a-ati-litiresq-alohun-yoruba-fumu-arugba-ati-ba-orun-gaa-gege-bi-awota. Accessed 18 Jan. 2025.
A.A, Adeyinka . "FllMU AGBELEWO G£GE BI OHUN-ELO IKONI NI A§A ATI LITIRESQ ALOHUN YORUBA: FUMU ARUGBA ATI BA$ORUN GAA GEGE BI AWOTA”". Afribary, Afribary, 23 Apr. 2021. Web. 18 Jan. 2025. < https://track.afribary.com/works/fllmu-agbelewo-g-ge-bi-ohun-elo-ikoni-ni-a-a-ati-litiresq-alohun-yoruba-fumu-arugba-ati-ba-orun-gaa-gege-bi-awota >.
A.A, Adeyinka . "FllMU AGBELEWO G£GE BI OHUN-ELO IKONI NI A§A ATI LITIRESQ ALOHUN YORUBA: FUMU ARUGBA ATI BA$ORUN GAA GEGE BI AWOTA”" Afribary (2021). Accessed January 18, 2025. https://track.afribary.com/works/fllmu-agbelewo-g-ge-bi-ohun-elo-ikoni-ni-a-a-ati-litiresq-alohun-yoruba-fumu-arugba-ati-ba-orun-gaa-gege-bi-awota